No.
2
Tonic Sol-fa

s: d, r, m. l: s. m.
d: f. m. r:.
r. f: m. r. m. s:
m. r: t’. l. s:-
s; s, d. m. l: s. m, m,
d: m. d. l:.
l. d: t. l. s. m:
r. m. m: r. d:-

Jesu, ran ‘sọji,
kọmi lati gbadu’a
Jẹki nle jẹ ‘bukun
f’ẹlomii loni
Gb’aiye mi ki O
si ṣe bi O ba ti fẹ
Oluwa ran ‘sọji
si bẹrẹ n’nu mi

Yoruba