No.
3
Tonic Sol-fa

m; r, d, d, d: d.
d. t. t. t. t. t:.
l. l. s. s. l. s:.
s. d. d. d. d.
r. m. r. d. l:.
l. t. s: f. m: r: d:-:

Mo ni ‘tẹlọrun,
Krist’ ngbe n’nu ọkan mi
Or’ofẹ Rẹ gba mi
Ejẹ Rẹ wẹ mi mọ
Ifẹ Rẹ ngbe n’nu ọkan mi
K’yo fi mi silẹ lai
Yo jẹ ogo titi lai

Yoruba