No.
4
Tonic Sol-fa

d, d, r. m. f: f:.
f, f, d. r. m: m:.
s, s, s. m. r: r:.
r. d. r. m: m:-
m. r. d: d:.
r, r, d. l. s: d:-
d. r. m: m:- r. r. d:-.

Arakunrin mi, njẹ
gbat’aiye yo gbina
‘Wọ ha fẹ f’Ọlọrun
ṣe ‘bi ‘sadi rẹ?
Pa mi mọ n’nu
Apat’ayeraiye
Ṣe ibi isadi mi

Yoruba