No.
6
Tonic Sol-fa

d. m. s:. l.
s. m. d:-
d: r:. r. d. r. m:-
d. m. s:. l.
s. m. d:-
d. r. m:. f.
m. r. d:-:

s:. l. s.
m. d’:-:
s:. l. s. m. r:-:
s:. l. s. m.
d’. t. l:
d’: m:. f.
m. r. d:-

Mo gbọ Jesu
wipe
Agbara rẹ kere
Alarẹ ṣọra
gbadua
Pipe rẹ mbẹ
lọdọ mi

Jesu san
gbogbo
Gbese ti mo jẹ
Ẹṣẹ ti
m’abawọn wa
O fọ mi fun
bi sno

Yoruba