No.
9
Tonic Sol-fa

m:-: m:-: m: r: d:
m: r: d: s:-: s:-: s:-:-: 7
f:-: f:-: f: m: r:
f: m: r: l:-: l:-: s:-:-: 7
s:-: d:-: d: t: l: t:-:
f:-: l:-: l: s: fe: s:-:
m:-: s:-: d: t: l: s:
m: d: m:-: r:-: d:-:-: 7

Mo fẹ ki ẹwa Jesu
han ninu mi
Gbogbo iwa tutu,
iwa mimọ Rẹ
Ẹmi ‘ye lat’ọrun,
Jọwọ wa tun mi da
Ki ẹwa Jesu le ma
han ninu mi

Yoruba