No.
19
Tonic Sol-fa

s:- m: s:- m:
s:- l: m:- d:
d:- l: d:- l: d:-:-:-
d:- d: r: d: l: s:- s:
d:- m: m:- s: s: f:
m: r:-: s:-:

s:- m: s:- m:
s:- l: m:- d:
d:- l: d:- l: d:-:-:-
d:- d: r: d: l: s:- d:
d: r: m: m:- r: s:-
f: m:- r: d:-:

1. Bi ọmọde
kekere li awa
le wọle
Bi ọmọde
kekere ti a ti
gb’ọkan rẹ la

T’o ndariji
ẹnikeji rẹ
tọkantọkan
A ngbagbe aṣiṣe ẹlomi ‘tori a
ngbe ‘nu Krist’

2. Bi ọmọde
kekere awa le 
k'aniyan
Oun banuje 
tọ Baba nibi
ite anu

Bi ọmọde
gbagbọ si
gbẹke le 'le ri Rẹ
bi ọmọde gba 'bukun Rẹ
ki o si ma w'Oju Rẹ

Yoruba