No.
20
Tonic Sol-fa
m. f. s: s: s: l: s: m:
m: r: d:. r. d: l: s:-:
d. r. m: m: m:
f: s: s:
l: l: s: m: m: d: r:-:
m. f. s: s: s: l: s: m:
m: r: d:. r. d: l: d:-:
d. r. m: m: s: l: s: m: d: r: m:. f.
m: r: d:-:
m. f. s:. l. s: m: s:-:
m. f. s:. l. s: m: r:-:
m. f. s: s: s: l: s: m:
d: r: m:. f. m: r: d:-:
‘Gba t’a ba de
‘lu ogo ni
T’Oluwa ti fi fun wa
T’a o si r’ọpọ
ibugbe ti On
ti pese si ‘lẹ
Nigbati a ba
ri I ninu Ogo
lori itẹ Rẹ
A o sọ itan na l’ọtun
F’anu t’O fihan
fun wa
Anu t’O fihan fun wa
Lati ṣe wa ni tirẹ
A o sọ itan na
l’ọtun
F’anu t’O fihan
fun wa
Yoruba