(H.C. 478)
No.
59
Tonic Sol-fa
d:. r. m: s:
l: s: s: m:
m:- m:. r. d:-:-
d:. r. m: s:
l: s: s: m:
m:- m:. r. d:-:-
d:. t. l: s:
l: s: s: m:
s: m: d:. t.
l: se: l: m:
d:. r. m: s:
l: s: s: m:
m:- m:. r. d:-:-
Ẹnikan mbẹ t’O
fẹran wa
A! O fẹ wa!
Ifẹ Rẹ ju
ti yekan lọ
A! O fẹ wa!
Ọrẹ aye nkọ wa silẹ
B’oni dun,
ọla le koro
Ṣugbọn ọrẹ yi
ko ntanni
A! O fẹ wa!
Yoruba