(Bro. 146)
s:. l. s: m:-: (2ce)
r:- r: t:-: d:- d: s:-:
l:- l: d:. t. l:
s:. l. s: m:-: (2ce)
r:- r: f:. r. t: d:-: m:-:
d: s: m:
s:. f. r: d:-:-:-
A-jin-jin, oru mimọ
Okun ṣu, ‘mọlẹ de,
Awọn oluṣagutan
nṣọna
Ọmọ ti o wa
l’oju ọrun
Simi n’nu alafia (2ce)
Yoruba