(Action 2:68)
No.
111
Tonic Sol-fa
s; d, m. m.
m. m. m:
r. d. r. d. d. l. d:
d. r. m. m.
m. m. s.
s. f. m. r:-:
s; f, m; m,
m. m. m:
r. d. r. d. d. l. d:
d. r. m. m.
m. d. r.
r. m; r, d:-:
N’nu Bibeli l’a
gbe ka
Nipa woli kan
t’a ran
S’awọn ara ilu kan
t’o kun f’ẹṣẹ
Gbogb’ awọn
ara ‘lu na
ko ni igbala
Jesu
Ẹru ba woli yi
lati lọ sibẹ
Ni ọrun,
nigboṣe
Ni ‘lu daradara ni
On y’o rohin
fun wa
ni kikun lọhun
Ni ‘ta wura
didan ni,
Ao di Jona lọwọ mu
On y’o rohin
fun wa
ni kikun lọhun
Yoruba