(S.S. 1-21)
No.
151
Tonic Sol-fa
s: l; s, m: s:
d: r; d, l:-
t: t; d, r: m:
d: t; l, s:-
s: l; s, m: s:
d: r; d, l:-
t: t; d, r: m: d:-:-
m: m: f:. m.
m. r. r. l. r:-
r: r: m:. r.
r. d. d. l. s:-
s: l; s, m: s:
d: r; d, l:-
t: t; d, r: m: d:-:-
Wa sọdọ Jesu,
maṣe duro
N’ọrọ Rẹ l’O
ti f’ọna han wa
O nduro li
aarin wa loni,
O nwi jẹjẹ pe, Wa
Ipade wa yio jẹ ayọ
Gb’ọkan wa ba bọ
lọwọ ẹṣẹ
A o si wa pẹlu
Rẹ, Jesu
Ni ile wa laelae
Yoruba