(Bapt .99)
No.
175
Tonic Sol-fa

d:. l. s: m: r:
s: f: m:
s:. s. l: t: d: r: d: t:
d:. t. l: s: f: m: m: r:
d:. r. m: d: s: s: d:-
m:. r. d: r: d:-
t:- d:-:-

Wa, Iwọ Jesu
t’a nreti,
T’a bi lati da ni nde
Gba wa lọw’ẹru
at’ẹṣẹ
Jẹ k’a ri isimi Rẹ (2ce)

Yoruba