(Bro. 278)
No.
185
Tonic Sol-fa

m; f, s: d:
m; r, d; l, d:
t; l, s:. m. s; d, r:-
m; f, s: d:
m; r, d; l, d:
t; l, s. d:. t; r, d:-

m; f, s; m, s:
d; t, l; f, l:
t. l. s:. m. s. d. r:-
m; f, s; m, s:
d; t, l; f, l:
t. l. s. s:. t; t, d:-

Ayọ bi odo lo ti nṣan
Gbat’Olutunu ti de;
Yo ba wa gbe
titi laelae
N’nu ọkan onigbagbọ

Itunu didun,
itunu mimọ,
Fi idaniloju kun mi;
Jesu ba igbi omi
okun wi
Idakẹrọrọ si de

Yoruba