(Elim Choruses 621)
No.
196
Tonic Sol-fa

d. r. m:. r. m: m:
s: f: m:-:-:
d: r: r: m: f:- t: d:-:-:
d. r. m:. r. m: m:
s: f: m:-:-:
m: r:. m. r: l:
t: d: r:-:-:

m: f:. m. f:
r: s: f: m:-:-:
s: l:. s. l:
s: m: d: r:-:-:
d. r. m:. r. m:
m: s: f: m:-:-:
d: r: r: m: f:- t: d:-:-:

Fi aye rẹ rubọ f’Ọlọrun
Oun lo nke si Ọ loni
Fi aye rẹ rubọ f’Ọlọrun
Jẹ ipe Jesu nisisiyi

Oko ti pọn fun ikore
Alagbaṣe ko pọ niye
Fi aye rẹ rubọ
f’Ọlọrun
Oun lo nke
tantan si Ọ

Yoruba