(S.S. 4-96)
No.
204
Tonic Sol-fa

s: d:- t: l: s:-
s: s: l: s: l:
t: d:- s:
s: l: s: f: m:
l: s: f: m:
r:- s:. s. s:-:

s: m: s: s: s:
l: s: s:
s: m: s: s: s:
l: s: s:-
d:- r: r: m:. r. d:
d: r:- d: t: d:-:

Awọn iya Salẹm
gb’ọmọ wọn
tọ Jesu lọ
Awọn ọm’ẹhin
Rẹ sọ fun
won pe, ẹ pada

Ṣugbọn ki nwọn
to yipada,
Jesu gbe wọn, O
sọ wipe
Ẹ jẹ k’awọn ọmọde
wa sọdọ Mi

Yoruba