(S.S. 4-95)
No.
205
Tonic Sol-fa

s; s, s; s, s; f, m; s, d; r, m; m, m; r, d: d; t, l; l, l; t, d; t, d; l, s; l, s; m, s:
s; s, s; s, s; f, m; s, d; r, m; m, m; r, d: d; d, r: r; r, d: t: d:-:-

s: s: m; s,
d; r, m:- d:-
l: l: d; t, d; l, s:- m:- s: s: m; s, d; r, m:- d: d: r: r: d: t: d:-:
s; s, d: m: d: (2ce)
s; s, d: m: r: d: r:-:

s; s, d: m: d: (2ce)
m: r:. d. t: l: s:-:
s: d: m. r. d: t: l: l: l: l: r: f. m. r: d: t: t: t: s: s':. s. m:. m. f. s. f. m. r: s':
m:. f. m: r: d:-:

Mose mu orilẹ-ede kan
jade l’oko ẹru
Ọlọrun nṣe amọna wọn
l’ọsan ati li oru
O fun wọn li ounjẹ
lat’ọrun wa,
aṣọ wọn ko gbo

Nwọn de Okun Pupa
Bawo ni Mose
ṣe kọja (3ce)
Ninu Okun
Pupa?
O wẹ kọja bi?
Ọkọ lo wọ bi?

O fo kọja
okun bi?
Nwọn gbe
kọja bi?
Bawo ni o
ṣe kọja
Okun Pupa?

Ọlọrun ni ki o
na ọpa rẹ
Sinu Okun Pupa,
Okun Pupa pin
si meji
Nwọn kọja ni
iyangbẹ ilẹ

Yoruba