No.
246
Tonic Sol-fa

d; r, m: m; m, f:
m; re, m:- d:
m; f, s: s: l: s; fe, s:-:
s: l: f. m. r: m. f. s:- m: r: d: t. d. r: d:
t: d: r: r:
m: m. m. fe: m: s:-:

s,; s, d: d; d,
r: m: m:- r:
r; m, f: f; f,
m: r: s:-:
s: d’: d: t: l; l,
s: m: d: f:
m: m; m, m: r: d:-:

Ao sọ itan kan
fun gbogbo aye
T’y o fa ọkan
wọn s’otitọ
Itan otitọ at’ adun
T’alafia at’ imọlẹ
T’alafia at’ imọlẹ

Tori oru yo
di owurọ
Owurọ yo d’ọsangangan
Ijọba Jesu yo
wa l’aye
‘Jọba ifẹ oun mọlẹ

Yoruba